Prio | Original string | Translation | — |
---|---|---|---|
There are %s questions in this survey. | Ìbéèrè %s ló wà nínú àkójọpọ̀ ìbéèrè yìí | Details | |
There are %s questions in this survey. Ìbéèrè %s ló wà nínú àkójọpọ̀ ìbéèrè yìí
You have to log in to edit this translation.
|
|||
Please confirm you want to clear your response? | Jọ̀wọ́ fi ìdíi rẹ̀ múlẹ̀ wípé lootọ lo fẹ́ pa ìdáhùn rẹ rẹ́? | Details | |
Please confirm you want to clear your response? Jọ̀wọ́ fi ìdíi rẹ̀ múlẹ̀ wípé lootọ lo fẹ́ pa ìdáhùn rẹ rẹ́?
You have to log in to edit this translation.
|
|||
Token: | Kóòdù àṣírí: | Details | |
To participate in this restricted survey, you need a valid token. | Lati lè kópa nínú àkójopọ̀ ìbéèrè yìí, o nílò lati ní kóòdù àṣírí kan tó ń ṣiṣẹ́ | Details | |
To participate in this restricted survey, you need a valid token. Lati lè kópa nínú àkójopọ̀ ìbéèrè yìí, o nílò lati ní kóòdù àṣírí kan tó ń ṣiṣẹ́
You have to log in to edit this translation.
|
|||
Language: | Èdè: | Details | |
Show "There are X questions in this survey": | Ṣe afihan "Ìbéèrè X ló wà nínú àkójọpọ̀ ìbéèrè yìí" | Details | |
Show "There are X questions in this survey": Ṣe afihan "Ìbéèrè X ló wà nínú àkójọpọ̀ ìbéèrè yìí"
You have to log in to edit this translation.
|
|||
Load now | Gbée jade báyìí | Details | |
Exit and clear survey | Kúrò kí o sì pa ìwé ìbéèrè náà rẹ́ | Details | |
Exit and clear survey Kúrò kí o sì pa ìwé ìbéèrè náà rẹ́
You have to log in to edit this translation.
|
|||
Answers cleared | A ti pa àwọn ìdáhùn rẹ́ | Details | |
Continue? | Tẹ̀síwájú? | Details | |
Next | Ohun tó kàn | Details | |
You can load a survey that you have previously saved from this screen. | O lè gbé àkójọpọ̀ ìbéèrè kan ti o ti fi pamọ́ tẹ́lẹ̀ jade ní ojú ìran yìí | Details | |
You can load a survey that you have previously saved from this screen. O lè gbé àkójọpọ̀ ìbéèrè kan ti o ti fi pamọ́ tẹ́lẹ̀ jade ní ojú ìran yìí
You have to log in to edit this translation.
|
|||
Type in the 'name' you used to save the survey, and the password. | Tẹ 'orúkọ' tí o lò lati fi àkójọpọ̀ ìbéèrè náà pamọ́ s'íbí, àti ọ̀rọ̀-àṣírí náà | Details | |
Type in the 'name' you used to save the survey, and the password. Tẹ 'orúkọ' tí o lò lati fi àkójọpọ̀ ìbéèrè náà pamọ́ s'íbí, àti ọ̀rọ̀-àṣírí náà
You have to log in to edit this translation.
|
|||
Saved name: | Orúkọ tí o ti fi pamọ́: | Details | |
Password: | Ọ̀rọ̀ àṣírí: | Details | |
Export as